Gbajugbaja olorin ọmọ Naijiiria, Don Jazzy ti ṣalaye pe bo ṣe ṣegbeyawo ni nnkan bii ọdun mejidinlogunsẹyin ṣugbọn ti igbeyawo naa tuka. Don Jazzy lo sọ ọrọ naa loju opo Instagram rẹ, nibi to ti sọ pe ...