Laipẹ yii ni iroyin jade pe Ọba Apetumodu ti ilu Ipetumodu ni ipinlẹ Ọṣun, Ọba Joseph Oloyede ti ri ẹwọn he lorilẹede Amẹrika nitori ẹsun jibiti to niiṣe pẹlu owo iranwọ lasiko ajakalẹ arun COVID-19 ...