Oludari agba fun akanse isẹ fun gomina tipinlẹ Eko, Mobolaji Ogunlende, ti sọrọ nipa ile alaje meje to da wo lulẹ ni agbegbe Banana Island, Ikoyi nilu Eko. Irọlẹ ọjọru ni ile alaja meje naa da wo lulẹ ...
Dokita Abiola Idowu tọ jẹ Ọga agba fun ile iṣẹ ti ohun risi abẹwo si awọn ibudo ilera ati iforukosile fun awọn ile iwosan ipinlẹ Eko ti kede pe Ipinlẹ Eko ti ni akọsilẹ aarun ti wọn n pe ni aarun ...